_Àjọ̀dún Ọdún Ọmọ Ìganmọdẹ, 2021: Ẹ ṣeun, bí ẹ ti jẹ́ ìpè wa_

 _Àjọ̀dún Ọdún Ọmọ Ìganmọdẹ, 2021: Ẹ ṣeun, bí ẹ ti jẹ́ ìpè wa_ 


*Gbogbo wa la óò tẹ́wọ́ gbare tó pọ̀, bí a ti ń tiraka fún ìdàgbàsókè Ilẹ̀ Ọ̀tà*



Àwọn Alákòóso Ètò Àjọ̀dún, tí Ààrẹ Ayọ̀délé Bánkọ́lé ń darí, gẹ́gẹ́ bí aṣojú fún Kábíèsí Ọlọ́tà ti Ìlú Ọ̀tà, Ọlọ́fin Àpésìn Olóde, Aláyélúwà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Adéyẹmí Ọbalánlẹ́gẹ́, PhD (Lánlẹ́gẹ́ Ẹkùn Kejì, Àrolé Ìganmọdẹ), pẹ̀lú àwọn ọ̀tọ̀kùlú láàfin Ọlọ́tà àti gbogbo àwọn ènìyàn àtàtà nínú ìlú Ọ̀tà Ilẹ̀ Àwórì (nílé, lóko àti lẹ́yìn-odi) ni a para pọ̀ gbé òṣùbà káre fún Ẹni-Ọ̀wọ̀ tí a pè, Ọlọ́lájùlọ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ògùn, Ọmọọba Dàpọ̀ Abíọ́dún, MFR, Olórí àwọn Agbátẹrù Àjọ̀dún Ọmọ Ìganmọdẹ, Onímọ̀-Ẹ̀rọ Noimot (aya) SÀLÀKỌ́-OYÈDÉLÉ, Bàbá wa níbi Ètò-Àjọ̀dún, H. E. Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ GCFR àti Alága níbi Àjọ̀dún wa, Aṣojú-Ìgbìmọ̀-Aṣòfin-Àgbà Akin Babalọlá Ọdúnsì (Máyégún ìlú Ọ̀tà), gbogbo àwọn olùgbé àti ọmọ bíbí Ilẹ̀ Ọ̀tà Àwórì, gbogbo olólùfẹ́ wa, pẹ̀lú àwọn ènìyàn àtàtà tí wọ́n fi ọwọ́ sowọ́ pọ̀ pẹ̀lú wa láti ṣe àṣeyọrí Àjọ̀dún Ọdún Ọmọ Ìganmọdẹ ti 2021 yìí.


Inú wa tún dùn púpọ̀ láti gbé oríyìn fún gbogbo àwọn wọ̀nyí, nípa ẹ̀dáwó àti ọọrẹ tí wọ́n gbé kalẹ̀:👉👇👇


*Ẹni-Ọ̀wọ̀ (Olóyè) Jídé Ojúko (Olótùú Ọ̀tà)- #150, 000*


*Aṣojú-Ìgbìmọ̀-Aṣòfin-Àgbà Adéọlá  Ọlámilékan Solomon (YAYI)-* #10M


*Adémọ́lá Elétùú Asorota:* #500, 000


*Aṣojú-Ìgbìmọ̀-Aṣòfin-Àgbà Tolú Ọdẹbíyì-* #2M


*Aṣojú-Ìgbìmọ̀-Aṣòfin-Àgbà Akin Ọdúnsì-* #1M


*Aṣojú-Ìgbìmọ̀-Aṣòfin-Àgbà (Ọmọọba) Gbọ́láhàn Dàda-* #500, 000


*Ẹni-Ọ̀wọ̀  Jimoh Ojúgbélẹ̀-* #1M


*Ẹni-Ọ̀wọ̀ Olúṣọlá Shotayo (Bọ̀rọ̀kìnní)-* #1M


*Ẹni-Ọ̀wọ̀ (Amojú-Ẹ̀rọ) Túnjí Akinòsì-* #250, 000


*ỌDÚN ỌMỌ ÌGANMỌDẸ: ÌPÍNSÍSỌ̀RÍ ÀWỌN TÍ WỌ́N DÁWÓ*


 _Ẹ ṣeun púpọ̀ fún gbogbo ìrànlọ́wọ́ tí ẹ ti ń ṣe..._ 


 *ÌPÍN A: ÀWỌN ÌGBÌMỌ̀ ÀÀFIN ỌLỌ́TÀ* 

 

i.) Olóyè Àgbà Abímbọ́lá Dàda (Ìyálájé Ìlú Ọ̀tà, Ilẹ̀ Àwórì)- #200, 000


ii.) Olóyè Àgbà Olúkẹ́mi Adéníji Adéògún- #100, 000


iii.) Olóyè Àgbà Ọláńrewájú Baṣọ̀run- #200, 000


iv.) Olóyè Àgbà Gàníù Dàda- #100, 000


v.) Olóyè Àgbà Adédayọ̀ Akíndélé Ẹlẹ́kù- #50, 000


vi.) Olóyè Àgbà Bámiṣayé Fádípẹ̀: #50, 000


*ÌPÍN B: ÀWỌN BAÁLẸ̀*


i.) Baálẹ̀ Akíntọ́lá Ahmed (Baálẹ̀ Ìṣaka)- #100, 000


ii.) Baálẹ̀ Sunday Bámiṣebí- #10, 000


iii.) Baálẹ̀ Lukman Sánní-*#20, 000


 *ÌPÍN D: ÀWỌN ÌJÒYÈ ỌLỌ́TÀ* 


i.) Ààrẹ (Surv.) Ṣẹ́gun Ọṣìfẹ̀sọ̀ fnis àti Yèyé Ààrẹ Atúnlùúṣe-  #250, 000


ii.) Olóyè  Ọláyínká (Aya) Șómóyè- #100, 000


iii.) Olóyè  Olúṣadé (Aya) Ògúnwálé - #20, 000


iv.) Olóyè Raymond Fádáyìíró (Baàmọ̀lú Ọ̀tà):  #100, 000


v.) Erelú Atúnwàṣẹ̀, Ọmọọba Adéníkẹ̀ẹ́ Akíndélé Ẹlẹ́kù: #200, 000


vi.) Olóyè Fáṣọlá Ifáníyì (Àràbà Ọ̀tà): #50,  000


vii.) Olóyè Olúṣọlá Rasaq Șótáyọ̀ (Bọ̀rọ̀kìnní Ọ̀tà, Ilẹ̀ Àwórì): #200, 000


*ÌPÍN E: ÀWỌN AGBOOLÉ*


i.) Agboolé Elédì Àtàlà- #50, 000


ii.) Agboolé Bánkọ́lé- #20, 000


iii.) Agboolé Òjó Séríkí- #50, 000


*ÌPÍN Ẹ: ÀWỌN LẸ́GBẸ́LẸ́GBẸ́/ÌJỌ/ÌGBÌMỌ̀* 


i.) Ọ̀tà Gravity Foundation- #300, 000


ii.) Ìgbìmọ̀ Ọ̀dọ́ fún Ìdàgbàsókè Ìlú (Ìjànà Youth Development Council)- #5,000


iii.) Ẹgbẹ́ Ọmọ Ìganmọdẹ (Ìganmọdẹ Club): #200, 000


iv.) Ìgbìmọ̀ Ọ̀dọ́ fún Ìdàgbàsókè Ìlú Orúba (Orúba Youth Development Council): #5,000


*National Council for Women Societies:* #5, 000


*Osi Council of Chiefs:* #20, 000


*Club 15:* #25, 000


*Lions Club(Through Gbenga Kehinde):* #25,000


*Ìpamẹ̀sán Òkè in Council (Nipasẹ̀: Baálẹ̀ Jámíù Kọ́mọláfẹ́):* #50, 000


*Ẹgbẹ́ Gbọ́baníyì:* #50, 000


*Gbádéga Royal Sisters:* #25, 000


*Ẹgbẹ́ Bọ́bagbadé:* #30, 000


*A1 Genesis Social Club:* #25, 000


*Ọlọ́tà Progressive Baálẹ̀s:* #50, 000


*Committee of Friends (Ọ̀tà Central):* #20, 000


*Ọ̀tà 80's:* #20, 000


*PDP Adó-Odò/Ọ̀tà LG:* #25, 000


*Ìgbìmọ̀ Ìjòyè Ìlú Ìjànà:* #10, 000


*Egbẹ́ AMORAN: Nípasẹ̀ Comrade Kamal Kelani:* #100, 000


*Ìgbìmọ̀ Ìjòyè Orílé Ẹ̀rìnkò:* #25, 000


*Àwórì Elite Sisters:* #25, 000


*Ọ̀tà Elites Club:* #10, 000


*Ẹgbẹ́ Bọ́baṣẹ̀yẹ:* #50, 000


*Mọ̀lẹ́bí Òrìṣàádáre:* #20, 000


*ÌPÍN F: ÌGBÌMỌ̀ ELÉTÒ ÀJỌ̀DÚN ỌMỌ ÌGANMỌDẸ*


i.) *Ààrẹ Délé Bánkọ́lé*- #500,000 (Alága)


ii.) *Ọmọọba Fẹ́mi  Fádínà*- #200,000


iii.) *Erelú Afèdèṣẹwà, Àlàájà Kàfáyát Oríṣilẹ̀*- #50,000


iv.) *Olóyè Tèmitáyọ̀ Ìdòwú*- #250, 000


v.) *Ẹni-Ọ̀wọ̀ Sheriff Músá:* #50, 000


vi.) *Ọ̀gbẹ́ni Kúnlé Șómọ̀rìn:* #100, 000


vii.) *Ẹni-Ọ̀wọ̀ Wàsíù Lawal:* #50, 000


*ÌPÍN G: ÀWỌN Ọ̀TỌ̀KÙLÚ*


 *Saheed OYÈDÉ*- #1, 000


 *Ọládayọ̀ Gafar Asánbẹ-* # 2,000


 *ÒGÚNGBÀYÍ ABDULHAZEEM ADÉMỌ́LÁ*- #2,000


 *Ọmọọba Ọ̀kẹ́ OYÈDÉ (NYP, OGUN WEST)-* #1,500


 *ÌȘỌ̀LÁ Sauban Àlàdé Orí-Àrán*- 1000


*Tèmitáyọ̀ Agẹmọ-Òkúbóyèjọ (Naijababe)*- #250, 000


 *MOBỌ́LÁJÍ ÀDÌÓ DÀDA*- #30,000


 *Habib Tọbalàṣẹ-* #50,000 


 *ACP Lateef Ahmed-* #300,000


*Dr. Kẹ́hìndé Ọdúnsì-* N250,000


*Bíọ́dún Adéníran-* #50,000


*SÀLÀKỌ́ Gbọ́láhàn Sàmínù-* #100, 000


*Ọmọọba Gàníù Adéwálé Adégbìtẹ́-* #50, 000


*Balógun Rótìmí Ismail-* #50,000


*Lai Taiwò (Diaspora)-* #300, 000


 *Ládiípọ̀ Olukogbon-* #50,000


*Akinwale Ismail Adeshina-* #5,000


*Ọmọọba Gbolaga Akinboyede*- #300, 000


*Tunde Kasali-* #250, 000


*Mrs Falilat Ajoke Bishi Aina-* #150, 000


 *Obasanya Rasak*- #150, 000


 *Mr Akinolu Akinbiyi (Jasco)-* #315,000


*Kosebinu Olumide-* #2,000


 *Dapo Ajibola Amosu-* #500,000


 *Ogunde Adebola-* #100, 000


 *Lawal Abayomi Kazeem-* #10,000


 *Dr. Babajide Salako:* #75,000


 *Dr. Kabir Alani Asalu-* #10, 000


 *Akindele Taiwo Bolaji* # 5,000


*Sẹ́nétọ̀ Gbọ́láhàn Dàda*- #250, 000


*Justice Atinuke Fadeke Oluyemi-* #100, 000


*Hon. Kolawole Ramon Salako(SSA)*- #50,000


*Mr Mujeeb Afolabi Akinde* - #100, 000


 *Kosebinu Olumide:* #50, 000


*Faruk Olalekan Aiyedogbon-* #2, 000


*Aderinoye Olorunsogo:* #20, 000


*Alhaja Mistura Bashorun:* #10, 000


*Adesegun Tunde Ogungbayi:* #2,000


 *Ismaila Akinboyede:* #2,000


*Quadri Adewale Lawal Obawole:* #200, 000


 *Samson Dosumu:* #5,000


*Bukola Fadina:* #2, 000


*Jimoh Musibau Alade:* #30, 000


*Adewoye Gbenga Joseph*: #20, 000


*Soboor Abiola:* #50, 000


*Mrs Remilekun M Opere-Taiwo-:* #20, 000


*Alhaja Rukayat Badmus:* #20, 000


*Comrade Kamal Kelani(Ksquare):* #100, 000

 

*Anonymous:* #100, 000


*Hon. Jimoh Ojugbele:* #1 000, 000


*Taofekat Ayo Oteshile:* #10, 000


*Gbenga Oni:* #100, 000


*Lookman Olusesi:* #100, 000


*Afolake Noimot Abiola:* #20, 000


*Ademola Yusuf Obalanlege:* #5, 000


*Alhaja Tawa Aroboto:* #5, 000


*Khalifa Abdulwasiu Akinboyede:* #2, 500


*Aliratu Kikelomo:* #50, 000


*Jonathan Orepo(Osi Baale Eledi Atala):* #5, 000


*Chief Samuel Aiyedogbon:* #50, 000


*Johnson Silifat Ajoke:* #25, 000


*Eletu Ademola Ashorota:* #500, 000


*Ogunde Adebola Taiwo:* #5, 000


*Chief Kamorudeen Ojuko:* #50, 000


*Awori Indigenous Staff, Ogitech:* #25, 000


*Hon. Sheriff Yussuf(Ibema):* #200, 000


*Alh. Alani Dada:* #50, 000


*Lateef Egbeyemi:* #20, 000


*Prof. Babatunde Lawal Salako:* #50, 000


*Adewale Adegoke Dada:* #20,000


*Osi Baale Ikowogbe(Chief Ismail Asade):* #5, 000


*Hon. Lamidi Musefiu:* #100, 000


*Steve Olarenwaju Rhodes:* #100, 000


*Yoruba Youth Council Worldwide:* #11, 500


*Salako Ismail:* #10, 000


*Deyola Williams:* #25, 000


*ÌPÍN H: ÀWỌN AṢOJÚ ILÉEȘẸ́ ŃLÁ*


i) *Eden Hotel and Suites-* #100, 000


ii) *Justrite International Stores:* #200, 000


iii) *Staunch Communications:* #20, 000


iv) *Avon Crown Cap:* #50, 000


v.) *Vintage Nest:* #50, 000


*Ìbuwọ́lù*:

Ọmọọba Adéyẹmí Sulaimon Olúṣesí, 

Akọ̀wé fún gbogbo Ìgbìmọ̀ Elétò Àjọ̀dún Ọmọ Ìganmọdẹ 2021

0/Post a Comment/Comments